Powered by gserviiz.com
Previous
Previous Product Image

The Gods Are Not to Blame (Three Crowns Books) – by O. Rotimi

$8.87
Next

The Beautyful Ones Are Not Yet Born (African Writers Series) by Ayi Kwei Armah

$6.36
Next Product Image

YORUBA LITERATURE- EEGUN ALARE

$3.75

YORUBA LITERATURE- EEGUN ALARE

Add to Wishlist
Category:

Description

Ní ìgbà àtijó,, eégún Alárè méjì kan wà ní Okeho (a kò mọ bí ti àtijó ni tàbí èyí tí ó wà báyìí lónìí) ni ilẹ̀ ìjọba Aláàfin Ọ̀yọ́, ọrẹ timotimo sì ni àwọn méjèèjì. Orúkọ ekinni a máa jẹ Òjé Larinnaka, tí èkejì a sì máa jẹ Dasofunjo. O se ni igba kan, Oje Larinnaka gbó pé are idán pípa kò wọ́pọ̀ ni apa ìlú kan, o si ro pe bí òun ba lo pidan fún wọn ní ibè, ọwọ òun yio ba ẹrú. Nípa bẹ́ẹ̀, ó pinnu ni ọkàn rẹ láti lọ sí ìlú náà dandan. Kí Oje Larinnaka to máa pale ìrìn-àjò maa mọ, ó fi lọ ọrẹ rẹ Dasofunjo, ó si gba a ní ìyànjú pé kí ó jẹ ki awon dijo lọ sí àjò náà:ṣùgbọ́n Dasofunjo so fún un pé òun kò ní lè lọ nitoripe idiwo ilé tí enia kò gbọ́dọ̀ fi silẹ lọ s’ajo poju f’oun. O wa gbàdúrà pé kí Ọlọ́run ṣamọ̀nà ọrẹ òun :kí ó lọ rere, kí ó bo rere Lehin àdúrà yi, Oje Larinnaka so fún ọrẹ pé òun yio tún de odò rẹ kì òun to lọ si àjò naa, òsì dìde lọ sí ilé rẹ. Bí ó ti délé ni ó so fun àwọn ẹbí àti aladugbo rẹ nípa ìrìn-àjò tí ó nlọ, o si tún sọ fún ìyàwó kansoso tí ó ní pelu. Ìyàwó rè náà tí a npe ni iyadunni tí lóyún sinú ni àsìkò yí. Bí ó ti sọ fún wọn tán ni o ba npalemo

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “YORUBA LITERATURE- EEGUN ALARE”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Recently Viewed Products

Shopping cart

1

Subtotal: $45.88

View cartCheckout